YBH 417

JESU f’ eje Re raw a

1. JESU f’ eje Re raw a,
E jek’ a sunm’ Olorun;
Opo nsina yi wa ka;
K’ anu mu wag badura, –
Pe ki awon t’ o fo ‘ju,
Laipe le r’ ona oto.

2. Oluwa, ji nwon yika,
Ki nwon mo ‘pe ayo na;
Eru esu lekan ri,
Ma jeki nwon s’ eru mo;
Oluwa, awa nwo O;
D’ elese ‘ gbekun sile.

3. A gbo ‘rohin ogo Re,
Ohun t’ apa Re ti se;
Opo so t’ ipa Re ri,
A ba tun le ri sa ni!
Mu nwon soji, Oluwa;
Ipa iyin na Tire.

(Visited 516 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you