YBH 418

WA, Oluwa, l’ anu tun wa

1. WA, Oluwa, l’ anu tun wa,
Pelu ‘pa ‘p’ okan da,
Ongbe ojo np’ oko Sion,
Masai ro s’ ori re.

2. Okan wa kun f’ are kikan,
Lati ri b’ elese,
Ti nte si iku ailopin,
Li airi iranwo.

3. “Jesu, wa pelu ‘pa ‘soji,”
L’ awon enia Re nke;
Mu ‘gbala wa ni sa anu,
Ma jek’ elese ku.

4. Jek’ elese ro s’ ile Re,
Ki nwon ho isegun,
Gbana l’ edun wa y’o d’ ayo,
Ekun, d’ orun iyin.

(Visited 264 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you