1. WO ‘le ‘wo enit’ a bukun,
O ki tun s’ alajo;
A fi gbogbo okan gba o,
‘Wo arakunrin wa.
2. Owo ‘dapo, at’ okan ‘fe,
On li a na si o;
Ni kiko aiye, o pinya
L’ ara ohun asan.
(Visited 171 times, 1 visits today)
1. WO ‘le ‘wo enit’ a bukun,
O ki tun s’ alajo;
A fi gbogbo okan gba o,
‘Wo arakunrin wa.
2. Owo ‘dapo, at’ okan ‘fe,
On li a na si o;
Ni kiko aiye, o pinya
L’ ara ohun asan.
We promise not to spam you