YBH 423

ARA n’nu Krist’, nitori Re

1. ARA n’nu Krist’, nitori Re,
A fi t’ okantokan gba o;
K’ a le jumo je ayo ti
Ko s’ en’ti fun ni lehin Re.

2. K’ Enit’ a pe nipa ‘ke Re,
Ran Emi ‘re Re sokale,
K’ O jeki ede wa k’ o dun,
K’ okan wag bona fun ife.

3. Gb’ onigbagbo ba pe bayi,
Ero aiye a d’ igbagbe;
A nfe lati s’ oro en’t’o
Ku, t’ O joba fun wa nikan.

4. Ao, so t’ ise at’ oro Re,
T’ iya t’ O je fun wa l’ aiye,
T’ ona t’ O la fun ririn wa,
T’ ohun t’ O nse l’ owo fun wa.

5. Bi akoko ti nrekoja,
Ao feran, ao sin n’ iyanu;
Ma reti ojo ogo ni
Ti ao pe li aipinya mo.

(Visited 151 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you