1. WO ‘le, ‘wo alabukunfun;
Wa l’ oruko Jesu owon;
A f’ ohun kan ke, “Ma wole,”
A ro pe Jesu kio pelu.
2. Ayo t’ aiye ko le fun ni
Ao f’ isokan wa idi re,
Nipa idapo nin’ emi,
At’ ife t’ o mu wa d’ okan.
3. B’ a si ti nlo l’ aiye ekun,
Ao f’ ayo at’ edun wa han;
Ao pin n’nu eru ara wa,
Ka ise ara si ti wa.
4. A tun o ki ni, “Ma wole,”
Gba idaloju ife wa;
A! ki gbogbo wa ko le pe
Y’ ite Olorun ka l’ oke.
(Visited 138 times, 1 visits today)