YBH 425

ENYIN enia Olorun

1. ENYIN enia Olorun,
Mo ti kiri aiye ka,
To ‘pa ese on ‘kanu,
Nko r’ itunu n’ ibikan.

2. Okan mi pada sin yin, –
Emi isansa, mo de;
Nibi pepe nyin ba njo,
E jo, gba mi s’ isimi.

3. Emi k’yo nikan rin mo,
Bi ategun at’ igbi;
‘Bugbe nyin yio je ‘le mi,
‘Busun nyin, iboji mi.

4. T’ emi ni Olorun nyin;
Jesu nyin yio je t’ emi;
Aiye ko le tun fa mi;
Mo ko gbogb’ osa sile.

(Visited 179 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you