YBH 426

JESU, ‘ Wo Olus’-agutan

1. JESU, ‘ Wo Olus’-agutan,
Pa agbo Re kekere mo;
Gb’ awon agutan Re wonyi,
Ma jekii nwon ko gbo lai.

2. Dabobo nwon labe orun,
Sin nwon lo sib’ omi iye;
Ki nwon sun n’ ib’ oko tutu,
K’ O si f’ oju ‘ke Re so won.

3. Jo, ko nwon lati m’ ohun Re,
Ki nwon yo nigba nwon ba gbo;
Ki nwon ma sa fun alejo,
Lai mo ‘ke miran lehin Re.

4. M’ awon t’ o ku l’ ode wa ‘le,
K’ O si jeki iye nwon pe;
Gbana jek’ awon t’ aiye lo
Dapo mo agbo nla t’ orun.

(Visited 333 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you