YBH 428

MA f’ ara fun ‘danwo, nitor’ ese ni

1. MA f’ ara fun ‘danwo, nitor’ ese ni
Isegun kan yio f’ ipa miran fun o
Ma ja bi okunrin, segun ibinu
Ma tejumo Jesu, yio mu o la ja
‘Bere k’ Olugbala fi
‘Pa on ‘tunu fu o
On fe ran o lowo
Yio mu o la ja.

2. Ma ko egbe k’ egbe, ma soro ‘koro
Mase pe oruko Olorun l’ asan
Je eniti nronu at’ olotito
Ma wo Jesu titi, yio mu o la ja.

3. Olorun yio f’ ade f’ enit’ o segun
B’ a tile nsubu a fi ‘gbagbo segun
Olugbala wa yio f’ agbara fun wa
Ma wo Jesu titi, yio mu o la ja.

(Visited 1,930 times, 2 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you