YBH 43

LI o wuro Iwo o gbo

1. LI o wuro Iwo o gbo
Ohun mi, Oluwa;
S’ odo Re l’ emi o dari
Oju adura mi.

2. Si oke ti Jesu lo be
Fun awon enia Re;
Ti o fi irahun wa han
Baba Re l’ ori ‘te.

3. Oba niwa ju Eniti
Elese ko le gbe;
O ko l’ ayo si elese,
Ko le gb’ owo ‘tun Re.

4. Sugbon emi y’o wa ‘le Re
Lati to anu wo,
Emi k’y’o si ye lati sin
Ninu agbala Re.

5. Emi Re iba le ma to
Ese mi sir ere.
Ko mu ona ise mi han
Gbangba niwaju Re.

(Visited 389 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you