YBH 430

TO nwon, Baba si O

1. TO nwon, Baba si O,
To nwon si O;
Awon omo wonyi
Ti O fun ni,
Nipa ‘fe Re orun,
To nwon, Baba si O,
To nwon, Baba si O,
To nwon si O.

2. ‘Gbati aiye ba ndan,
T’ o nwo dara,
Ma jek’ ohun etan
Mu nwon sina;
Kuro n’ ipa danwo
To nwon, Baba si O,
To nwon si O.

3. Fun ‘ru nwon ni Jesu
Wa l’ omode,
O si gb’ aiye ese
L’ ail’ abawon;
A! ‘tori Re masai
To nwon, Baba si O,
To nwon si O.

4. ‘Gbagbo mi le s’ aipe
Sibe mo mo
P’ awon ore wonyi
‘Wo yio gba won;
A! gb’ okan won s’ odo,
K’ O si to nwon si O,
To nwon, Baba si O,
To nwon si O.

(Visited 1,380 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you