1. OLUWA sokale,
Bukun awon ‘mo ma,
Laipe, ki ife won le te
Si ore-ofe Re.
2. B’ o ti je ‘fe wa to
Lati ri ayo won,
Gbogbo ife wa si dapo,
Lati to nwon si O.
3. Tu Emi Re, Baba,
S’ ori irugbin wa;
A! mu sa t’ a nreti ni wa
T’yo se nwon ni Tire.
4. Jeki nwon gb’ oro Re,
Jewo oruko Krist’,
Kin won si tel’ En’t’ a gan ni
N’nu ‘tebomi l’ odo.
5. Beni k’ iran wa yi
Pepe mimo Re ka,
Lati wole fun ore Re,
Ko Jesu won l’ orin.
(Visited 240 times, 1 visits today)