1. JESU Oba, a pari eko wa,
Ma jeki Esu sa je l’ okan wa.
2. Jesu Oba, a s’ ope lowo Re,
T’ O ti fun wa li onje orun je.
3. Jesu Oba, ko s’ eko bi Tire,
Ihin Re dun pupo li eti wa.
4. Jesu Oba, Iwo li ao ma wo,
O ti ko wa be ninu oro Re.
5. Jesu Oba, n’ ijade wa lo yi,
A be O k’ O dabobo gbogbo wa.
6. Jesu Oba, ninu gbogb’ ose yi,
So wa, si mu wa ri ose ti mbo.
(Visited 179 times, 1 visits today)