YBH 439

ILE-EKO ojo ‘sinmi

1. ILE-EKO ojo ‘sinmi,
A, mo ti fe O to!
Inu mi dun mo daraya
Lati yo ayo re

2. Ile-eko ojo ‘sinmi,
Oore re p’apoju;
T’agba t’ewe wa nkorin re,
A nse aferi re.

3. Ile-eko ojo ‘sinmi,
Jesu l’o ti ko o;
Emi Mimo Olukoni,
L’o sin se ‘toju re.

4. Ile-eko ojo ‘sinmi,
Awa ri eri gba,
P’Olorun Olodumare
F’ibukun s’ori re.

5. Ile-eko ojo ‘sinmi,
B’orun nran l’aranju,
Bi ojo su dudu l’orun,
Ninu re l’ emi o wa.

6. Ile-eko ojo ‘sinmi,
Mo yo lati ri o,
‘Wo y’o ha koja lori mi
Loni, l’airi ‘bukun?

(Visited 757 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you