1. KEFERI nsegbe lojojo,
Egbegberun l’ o nkoja lo;
Mura Kristian s’igbala won,
Wasu fun won ki nwon to ku.
2. Oro, owo, e fi tore,
Na k’ e sin a kin won le ye;
Ohun ti Jesu se fun nyin
Kil’enyin iba se fun On?
(Visited 340 times, 1 visits today)