1. JESU bukun oro Re,
K’ o le tete f’ ipa han;
Ki elese gbo ‘pe Re,
K’ enia Re dagba n’nu ‘fe.
2. Bukun ise anu Re,
Fi agbara Re tele:
K’ ihinrere Re ka ‘le,
Tire n’ise at’ ogo.
3. Jesu so f’ aiye k’o yo,
Ran oto re kakiri,
K’ oril-ede gb’ ohun Re,
Ki nwon pada t’ Olorun.
(Visited 318 times, 1 visits today)