YBH 46

AKOKO ‘re gbat’ eda te

1. AKOKO ‘re gbat’ eda te,
Lati b’ Olorun re s’ oro,
Lati f’ edun ranse s’ oke,
Ati lati gb’ oro mimo.

2. Gbat’ aniyan aiye jowo
Ijoba aiya re lowo,
T’ ohun gbogbo nfi paroro
So ti ojo ‘simi’ mimo.

3. Gbat’ Olorun pa sunmo ni,
Lati f’ ayo gbo t’ enia Re,
Lati f’ opin si arokan,
Lati tan ekun asofo.

4. Ibanigbe Re ni fun ni,
Ni itowo ayo ti mbo,
Ni so ‘le aiye d’ ile re,
Ati ona ‘bode orun.

(Visited 207 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you