YBH 47

JI okan mi, ba orun ji

1. JI okan mi, ba orun ji,
Mura si ise ojo re;
Ma se ilora, ji kutu,
K’ o san ‘gbese ebo oro.

2. Ogo fun Enit’ o so mi,
T’ o tu mi lara l’ oj, orun;
Oluwa ijo mo ka ku,
Ji mi s’ aiye ainipekun.

3. Oluwa mo tune je je,
Tu ese ka b’ iri oro;
So akoronu mi oni,
Si f’ Emi Re kun inu mi.

4. Oro at’ ise mi oni,
Ki nwon le ri bi eko Re;
K’ emi fi ipa mi gbogbo
Sise rere ogo Re.

(Visited 1,075 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you