YBH 48

OLORUN kutu ohun Re

1. OLORUN kutu ohun Re
L’ o mu orun f’ ayo dide,
Inu re dun bi omiran,
Lati sare yi sanma ka.

2. Gege bi orun, mba le fi
Ayo se ise ojo mi,
Ki nfi iyara at’ ife
Te s’ ona ajo orun mi.

3. Fi eko Re s’ amona mi,
K’ O si gba mi si ayo re,
Ireti mi lehin eyi
Je tutu ati ailokun.

(Visited 148 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you