YBH 452

MA sise lo, mase sare

1. MA sise lo, mase sare,
Fi ayo sise Baba re;
Bayi ni Jesu se l’ aiye
Ko ha ye k’ awa ko se be?

2. Ma sise lo, l’ ojojumo,
Okunkun aiye fere de;
Mura si ‘se, mase s’ ole,
Ko ba gba okan re la.

3. Pupo pupo l’ awon t’ o ku
Ti nwon ko n’ ireti orun;
Gbe ina ‘gbagbo re, ma fi,
Ma fi si okunkun aiye.

4. Ma sise lo, ma yo pelu,
Lehin ise, ‘wo o simi;
O fere gb’ ohun Jesu na
Y’o ke tantan pe, “Emi de.”

(Visited 1,785 times, 2 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you