1. LO kede igbala Jesu
Gbogbo enyin onigbagbo
Fun ‘rugbin Sharon ka gbogbo,
Orile ede aiye yi.
2. Yio f’ agbala ‘na yi o ka
Yio f’ itara kun okan re
O pase fun iji lile
Iji lile dare roro.
3. Gbati ise wa ba pari
A o pade lai tun pinya mo
Pelu awon t’a ra pada
Ao se l’ oba awon Oba.
(Visited 322 times, 1 visits today)