1. OLUWA, jeki ore Re,
To ‘lu wa pel’ agbara Re;
K’ o le m’ eje ife re wa,
Fun Iwo Olugbala wa.
2. Ki gbogbo ‘le Olorun da
Orin ‘segun t’ iyin mimo;
Ki gbogbo ‘le Alafia
Di ibugbe Re, Oluwa.
3. Sibe ko je ayo wan la,
Lati rin bi n’ iwaju Re;
N’nu ‘lana ati eru Re,
K’ a gbiyanju titi d’ opin.
(Visited 239 times, 1 visits today)