1. NAIJIRIA, a ki o,
Orile wa owon
Eya, ede le yato
A duro ni ‘sokan,
Pelu ayo l’a o sin O
Ile t’a gbe bi wa.
2. Asia wa yio j’ ami,
Pe eto lo njoba;
Nigba ‘lafia tab’ ogun
Eyi ni ere wa
Lati fi le omo lowo
Asia ‘lailabawon.
3. Olorun gbogbo eda
Gbo adura wa yi
Je k’ a ni orile-ede
Nib’a ko re ni je
K’ alafia ati opo
Je ipin Naijiria.
(Visited 947 times, 1 visits today)