YBH 475

WA, jek’ a tun pilese ajo wa

1. WA, jek’ a tun pilese ajo wa,
K’ a b’ odun yipo,
K’ a ma duro tit’ Oluwa yio fi de.

2. Ife rere Re, jek’ a f’ ayo mu se,
K’ a malo ebun wa,
Nipa suru-ireti at’ ise-ife.

3. Aiye wa b’ ala, igba wa b’ odo
Nsan jade Kankan,
Akoko ti nsare si ko lati duro.

4. A tit a ‘fa na, igba si lo tan,
Odun Oluwa,
Si wa siwaju wa, aiyeraiye si de.

5. Gbogbo wa ‘ba lw wi l’ ojo wiwa Krist’ pe
“Emi ti lo ‘pa mi,
Mo ti sise mi tan, t’ O fun mi lati se.”

6. Gbogbo wa ‘ba le gbo l’ enu Oluwa wa,
“Iwo ti se rere!
Bo sinu ayo Mi, si joko l’or-ite.”

(Visited 183 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you