1. OLUWA fi apa Re han,
Si jek’a r’ ogo Re,
Ki gbogbo wa ri ami Re,
K’ o m’ okan lile ro.
2. K’ anu yow a ninu ebi,
Gbogb’ ese t’ a ati da,
Ki odun ti a bere yi,
Le pari pelu Re.
3. Ran Emi Re lat’ oke wa,
K’ a le fe Ojulo,
K’elese ti ko n’ ife ri,
Le ko lati feni.
4. Nigbat’ a ba de ‘waju Re,
N’ ile aiyeraiye,
Ki opo d’ ipo wa nihin,
Lati f’ iyin fun O.
(Visited 250 times, 1 visits today)