1. B’ ORUN l’ aiduro ti rin,
La odun ti o lo ja
Be l’ opo ti d’ opin won
A ki o si ri won mo.
2. A so won l’ ojo laiali,
Tiwon pari li aiye;
Awa duro die na,
Y’ o ti pe to a ko mo.
3. Gb’ ope f’ anu t’ o koja
Tun dari ese ji wa;
Ko wa b’ a ti wa k’ a ma
Se ‘ranti aiye ti mbo.
4. Bukun f’ewe at’ agba,
F’ ife Oluwa kun wa;
‘Gba ojo aiye wa pin
K’ a gbe odo Re l’ oke.
(Visited 213 times, 1 visits today)