YBH 485

OLUWA at’ ‘igbala wa

1. OLUWA at’ ‘igbala wa,
L’ o ko wa jo l’ ale oni,
Je ka gbe Ebeneser ro;
Odun t’ a ti la koja yi,
Ni on f’ore Re de l’ade
Otun l’ anu Re l’ owuro
Nje ki ope wa ma po si,
L’ osan, l’ale, nigbagbogbo.

2. Jesu t’ o joko lor’ ite,
L’ a fi halleluya wa fun;
Nitori Re nikansoso
L’ a da wa si lati Korin;
Ran wa lowo lati kanu,
Ese odun t’o ti koja
Fun ni k’ a loeyi ti nbo,
S’iyin Re ju odun t’ o lo.

(Visited 475 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you