1. NI akoko ipinya,
Jeki a fi ara wa,
S’ abe oju at’ okan,
Ore korikosun wa.
2. Jesu gbo adura wa,
‘Wo ti nso agutan
K’ anu at’ itoju Re,
Pa gbogbo okan wa mo.
3. K’ a l’ agbara n’ ipa Re,
F’ adun s’ irora gbogbo,
K’ o si da emi wa si,
Titi ao fi tun pade.
(Visited 500 times, 1 visits today)