YBH 490

K’ ORE-ofe Krist’ Oluwa

1. K’ ORE-ofe Krist’ Oluwa,
Ife Baba ailopin,
Oju rere Emi Mimo
K’ o t’ oke ba lori wa.

2. Bayi l’ a le wa ni ‘repo
Ninu wa at’ Oluwa;
T’ a si le ni ‘dapo didun,
Ayo t’ aiye ko le ni.

(Visited 1,140 times, 2 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you