YBH 491

OLORUN l’ odo eniti

1. OLORUN l’ odo eniti
‘Toju ife ti nwa,
Iforiti gbagbo ‘reti,
Ro ‘jo won lat’ oke.

2. Pin won fun olukuluku,
Bi won ti saini si
K’ ero wa b’ ebo turari
Le goke s’ odo re.

3. Je ki ojo na yara de
T’ iku ki yio si mo,
T’ ijoba re yio kun aiye
Pelu alafia.

4. Olorun l’ ojo ikehin
Gb’ ohun gbogbo pari,
Mu wa d’ orun ijoba Re
Paradise Orun.

(Visited 235 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you