1. LAB’ ese, ati l’ oke wa,
Ni ikilo tin dun,
Oku aimo ‘ye sun n’nu ‘le,
Orun si wa l’ oke.
2. Iku gun afefe l’ esin,
O wa ninu ‘tanna,
Awon igba ni aisan won,
Nwon si ni ewu sibe.
3. Pada, elese, n’ ewu re,
Nibikibi t’ o nlo,
Iho t’ o wa labe ‘le nso
T’ awon t’ a sin sibe.
4. Onigbagbo, e yipada,
K’ e si gba otito,
P’ awon t’ a sin si ‘le yio ji
Si ayo tab’ egbe.
(Visited 157 times, 1 visits today)