YBH 5

NIWAJU ‘te Jehofa nla

1. NIWAJU ‘te Jehofa nla,
Oril’-ede e f’ ayo sin;
Mo p’ On nikan ni Olorun,
O le da, Osi le parun.

2. Ipa Re laisi ‘ranwo wa,
L’ O famo da wa l’ enia;
Nigbat’ a sako b’ agutan,
O mu bo si agbo Re.

3. Enia at’ ike Re ni wa,
Emi at’ ara iku wa,
Ola t’ o to wo l’ a ba fun
Oruko Re Eleda Nla.

4. Ao fi orin kun ile Re,
L’ ohun giga l’ a o korin,
Ile y’o f’ egbarun ahon
Fi iyin kun agbala Re.

5. Ase Re gboro bi aiye,
Ife Re bi aiyeraiye,
Oto Re y’o duro sinsin,
Nigba odun ki y’o yin mo.

(Visited 468 times, 4 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you