YBH 6

E Yin Oluwa, e tun ohun se

1. E Yin Oluwa, e tun ohun se,
Lati korin Re ninu ajo nla;
E je k’ aiye yo ninu Eleda won,
K’ akobi igbala yo n nu Oba won.

2. Ki nwon f’ itara sin oruko Re,
Ki nwon si f’ ife Re han,
Enit’ O fi ife s’ ilekun oro,
Lati tan aini, lati bukun fun won.

3. Ninu ogo li awon enia Re,
Y’ o ko orin si Onibu-ore,
Ohun iho ayo won si Oba won,
Y’ o ka gbogbo aiye, y’o si de orun.

(Visited 396 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you