1. OKAN mi, oju re tun ri
Afemo ju ojo;
Lekan si, korin, ohun mi
S’ Oba t’ O je loke.
2. Oru d’oru np’ oruko re,
Osan tun pe l’ otun,
Ogb’ ile b’ ibukun Re,
T’ Ogbe nyi akoko.
3. On l’ oda ara mi duro,
Ahon mi o yin I,
Ese mi fe ru inu Re,
Sugbon ‘binu lora.
4. Oba, k’ igba mi je Tire,
Niwon bi mo ti wa;
Orun mi y’o fi erin wo,
Y’o m’oru didun wa.
(Visited 348 times, 2 visits today)