1. ARA, b’ a ko tile gbo
Ohun kan lat’ oke wa;
Sibe a mo pe loni,
Gbogbo ‘rora tan fun o.
2. kio d’ omije fun o,
Iwo omo Olorun,
Baba ti f’ iku didun,
Ti onigbagbo pe o.
3. Ara, ninu ‘reti yi
A fi o fun ekuru,
L’ ori re l’ a wa titi,
Ao fi pade li orun.
4. ‘Gbat’ a nsokun bi Jesu,
Iwo o sun b’ O ti sun,
Pelu Re ‘wo o simi,
A o si de o l’ ade.
(Visited 444 times, 1 visits today)