1. GB’ ohun t’ o orun wa ti wi
F’ awon mimo t’ o ku,
“Didun l’ orun oruko won,
‘Busun won n’ itura.”
2. “Nwon ku n’nu Jesu, orun won
Si kun fun ibukun!
Nwon bo low’ ese on ‘rora,
Ati gbogbo ibi.”
3. “Jina s’ aiye iyonu yi,
Nwon wa lod’ Oluwa;
Ise won l’ aiye osi yi
Pari l’ ere fun won.”
(Visited 578 times, 1 visits today)