1. KIKU n’nu Jesu, iku re
T’ a ki ji sinu re sokun,
Isimi t’ o ni itura,
Ti iku ko le yo lenu.
2. Kiku n’nu Jesu ti dun to,
A ba le ye fun orun yi,
K’ a fi igbekele korin,
Pe, “Iku itani re da?”
3. Kiku n’nu Jesu je ‘simi,
Ti ajinde re n’ ibukun,
Ko s’ eru ti yio ba ojo,
Agbara Olugbala je.
(Visited 389 times, 1 visits today)