YBH 514

GB’ ohun to t’ orun wa ti wi

1. GB’ ohun to t’ orun wa ti wi,
Bukun f’ oku onigbagbo
Nwon bo ninu lala aiye
Aiye ki yio tun mo won mo,
Ma sokun mo, Ma sokun mo,
Onigbagbo ma sokun mo
Onigbagbo ma sokun mo

2. Ese t’ onigbagbo nsofo,
F’ awon to sun ninu Kristi,
Gbati inu enia baje
Awon Angeli nyo l’ oke,

3. Onigbagbo to ku l’ aye,
F’ ibanuje f’ awon ara,
Sugbon awon ogun orun
F’ ayo gbe e’ ese Jesu.

4. Jesu si f’ oju ayo wo,
Omo odo na l’ ese Re,
O si fi iyonu kip e;
O seun omo odor ere.

5. Onigbagbo ma jafara,
Ninu ajo re l’ aiye yi,
Ki ade ogo je tire,
Pelu irawo ti ki sa;

(Visited 774 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you