YBH 516

NJ’ Onidajo yio wa

1. NJ’ Onidajo yio wa?
Nj’ oku yio ji dide?
Nje ko s’ eniti yio le sa
Kuro ni oju Re?

2. Ba’o l’ okan mi yio ti
Gba eru ojo na,
Nigbat’ orun ati aiye
Ba sa lo l’ oju Re?

3. Sugbon k’ ipe to mi
‘Bugbe awon oku,
Gbo ihin ti a tan kiri,
Lat’ inu ‘We Mimo!

4. Wa, elese, w’ anu
En’t’ ibinu Re po,
Sa si abe agbelebu,
K’ o r’ igbala nibe.

(Visited 193 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you