YBH 520

GBAT’ O ba de, gbat’ O ba de

1. GBAT’ O ba de, gbat’ O ba de,
Lati sir’ oso Re;
Gbogb’ oso Re iyebiye,
Awon ti O fe!
Bi irawo owuro, nwon ns’ ade Re l’ oso,
Ewa won o yo pupo, ewa f’ ade Re.

2. Yio ko jo, yio ko jo,
Oso ijoba Re;
Awon mimo, awon didan,
Awon ti O fe.

3. Awon ewe, awon ewe,
T’ o fe Olugbala,
Ni oso Re, iyebiye,
Awon ti O fe.

(Visited 8,766 times, 6 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you