YBH 521

OJO ‘dajo, ojo, eru

1. OJO ‘dajo, ojo, eru!
Gbo bi ipe tin dun to!
O ju egbarun ara lo,
O sin mi gbogbo aiye.
Bi esun na
Yio ti damu elese.

2. Wo Onidajo l’ awo wa,
O woo go nla l’ aso,
Gbogbo wa ti now ona Re,
Gbana ni nwon o ma yo.
Olugbala,
Jewo mi ni ijo na.

3. Ni pipe Re, oku yio ji
Lat’ okun, ile, s’ iye
Gbogbo ipa aiye yio mi,
Nwon o salo l’ oju Re,
Alaironu,
Yio ha ti ri fun O?

4. Sugbon f’a won t’ o jewo Re,
T’ nwon fe, tin won sin l’ aiye,
Yio pe, “Wa, alabukunfun;
Wo ‘ joba ti Mo fun nyin,
Titi aiye,
L’eo mo ‘fe at’ ogo Mi.”

(Visited 497 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you