1. JESU, Oluwa or’-ofe,
‘Wo imole oju Baba,
Kanga ‘mole aiyeraiye,
T’ ase Re l’ okun ale lo.
2. Wa, Orun ‘fe orun mimo,
Ran ase Re lat’ oke wa,
K’ O tan ‘mole Emi Mimo,
Sinu isale okan wa.
3. Be ni k’ a p’ ojo gbogbo mo,
Ki oro wa f’ irele han,
Ki osan wa fi ife tan ,
K’ orun wa wo ninu ‘reti.
4. Jesu, ojo gbogbo l’ o nmu
Aworan Re wa s’ okan wa;
A ba le ma ri ninu Re,
Olugbala wa titi lai.
(Visited 586 times, 1 visits today)