YBH 540

ALABUKUN n’nu Jesu

1. ALABUKUN n’nu Jesu
Ni awon om’ Olorun
Ti a fie je Re ra
Lati ‘nu iku s’ iye;
A ba je ka wa mo won,
Laiye yi, ati l’ orun.

2. Awon ti a da lare
Nipa ore-ofe Re;
A we gbogbo ese won,
Nwon o bo l’ojo ‘dajo;

3. Nwon ns’ eso ore-ofe;
Ninu ise ododo,
Irira l’ ese si won,
Or’ Olorun ngbe ‘nu won;

4. Nipa ej’ Odagutan,
Nwon mba Olorun k’ egbe,
Pelu Ola-nla Jesu,
A wo won l’ aso ogo;

(Visited 1,984 times, 2 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you