YBH 546

MASE huwa ese

1. MASE huwa ese,
Ma soro ese;
Omo Jesu l’ e se,
Omo Oluwa.

2. Krist je oninure,
At’ eni mimo;
Be l’ awon omo Re
Ye k’ o je mimo.

3. Emi ibi kan wa,
T’ o nso irin re;
O si nfe dan o wo,
Lati se ibi.

4. E mase gbo tire;
B’ o tile soro
Lati ba Esu ja,
Lati se rere.

5. Enyin to fe Jesu
Ese ife Re
Ke si K’Esu sile
Ati ona re.

6. Omo Kristi ni iyin,
E ko lati ba
Esu inu nyin ja;
E ma se rere.

7. Jesu l’ Oluwa nyin,
O se enire;
Ki enyin omo Re,
Si ma se rere.

(Visited 413 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you