YBH 547

GBATI Samueli ji

1. GBATI Samueli ji
To ‘igb’ ohun Eleda
Ni gbolohun kokan,
Ayo re ti po to
Ibukun ni f’ omo t’ o ri
Olorun nitosi re be.

2. B’ Olorun ba pe mi
Pe, ore mi li On,
Ayo mi y’ o ti to
Ngo si f’ eti sile,
Ngo sa f’ ese t’ o kere ju,
B’ Olorun sunmo’tosi be.

3. Ko ha mba ni soro?
Beni n’nu Oro Re?
O npe mi lati wa
Olorun Samuel;
N’nu Iwe na mo ka pe
Olorun Samuel npe mi.

4. Mo le f’ ori pamo
S’ abe itoju Re,
Mo mo p’ Olorun nbe
L’ odo mi n’ gbagbogbo
O ye k’ eru ese ba mi,
Tor’ Olorun sunmo ‘to si.

5. ‘Gbamba ka oro Re,
Ki nwi Samuel pe
Ma wi, Oluwa mi
Emi y’ o gbo Tire;
‘Gba mo ba si wa n’ile Re,
“Ma wi, ‘tori ‘ranse Re ngbo.”

(Visited 732 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you