YBH 552

JESU pe omode

1. JESU pe omode,
O gbe won s’ aiya Re;
O f’ owo Re gba won mora,
O si sure fun won.

2. Jesu gb’ omode yi,
T’ a gbe wa s’ ile Re,
Tikala Re se ni Tire,
K’ o dagba f’ ogo Re.

3. Gb’ awon omode wa,
Ti won nwa waju Re,
Si pese f’ awon ti ko ni,
Sure fun gbogbo wa.

(Visited 374 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you