1. SA dake, okan mi,
Oluwa re wa n’be,
Enit’ o ti se ileri,
Yio fe mu u se.
2. On ti fa o lowo,
O mu o de ‘hinyi,
Yio pa o mo la ewu ja,
Tit’ igba aiye re.
3. Nigbat’ iwo ti bo
Sinu wahala ri,
Igbe re na ki On ha gbo
T’ O si yo o kuro?
4. B’ ona ko tile dan,
Yio mu o de ‘le;
Sa ti wahala aiye tan,
O san fun gbogbo re.
(Visited 271 times, 1 visits today)