1. LARIN ewu at’ osi,
Kristian, ma te siwaju,
Roju duro, jija na,
K’ onje ‘ye mu o l’ okun.
2. Kristian, ma se te siwaju
Wa k’ a jeju ko ota;
E o ha beru ibi?
S’ e moyi Balogun nyin?
3. Je ki okan k’ yo;
Mu ‘hamora orun wo;
Ja, ma ro pe ogun npe,
Isegun nyin fere de.
4. Ma je k’ inu nyin baje,
On fe n’ omije nyin nu;
Mase je k’ eru ban yin,
B’ aini nyin, l’ agbara nyin.
5. Nje, e ma te siwaju,
E o ju asegun lo;
B’ op’ ota dojuko nyin,
Kristian, ete siwaju.
(Visited 449 times, 1 visits today)