YBH 59

JE ni imole ojo

1. JE ni imole ojo
Para kuro loju mi,
Lala mi rekoja lo,
Ngo ba Oluwa soro.

2. ‘Wo t’ oju Re ri yika,
Oba arinu r’ode,
Dari gbogbo ese ji,
T’ ikoko at’ igbangba.

3. ‘Mole ojo fere lo
L’ oju mi titi lailai,
‘Gba mba bo lowo ese,
Jesu gba mi sodo Re.

(Visited 289 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you