1. LAT’ ori pepe okan wa ,
Je ki orun dide;
Oluwa ma sai ba war u
Ebo asale wa.
2. Iseju at’ opo anu
L’ a fi s’ ojo oni,
Iseju nfo, sugbon anu,
O sare ta won yo.
3. Ojure at’ ayo titun,
Bere orin otun,
Tit’ ao fi yin O b’o ti ye,
Gba ife okan wa.
(Visited 410 times, 1 visits today)