YBH 590

SI pepe Oluwa

1. SI pepe Oluwa,
Mo mu ‘banuje wa;
‘Wo ki f’ anu tewogba
Ohun alaiye yi?

2. Kristi Odagutan
Ni igbagbo mi now;
‘Wo le ko ‘hun alaiye yi?
‘Wo o gba ebo mi.

3. ‘Gbati Jesu mi ku,
A te ofin l’ orun;
Ofin ko ba mi l’ eru mo,
‘Tori pe Jesu ku.

(Visited 172 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you